Johanu 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Juu wá bi í pé, “Àmì wo ni ìwọ óo fihàn wá gẹ́gẹ́ bíi ìdí tí o fi ń ṣe nǹkan wọnyi?”

Johanu 2

Johanu 2:8-25