Johanu 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹta, wọ́n ń ṣe igbeyawo kan ní Kana, ìlú kan ní Galili. Ìyá Jesu wà níbẹ̀.

Johanu 2

Johanu 2:1-9