Johanu 19:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Juu dá a lóhùn pé, “A ní òfin kan, nípa òfin náà, ikú ni ó tọ́ sí i, nítorí ó fi ara rẹ̀ ṣe Ọmọ Ọlọrun.”

Johanu 19

Johanu 19:1-8