Johanu 19:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí wọ́n dé ọ̀dọ̀ Jesu wọ́n rí i pé ó ti kú, nítorí náà wọn kò dá a lójúgun.

Johanu 19

Johanu 19:32-40