Johanu 19:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá sọ fún ọmọ-ẹ̀yìn náà pé, “Wo ìyá rẹ.” Láti ìgbà náà ni ọmọ-ẹ̀yìn náà ti mú ìyá Jesu lọ sílé ara rẹ̀.

Johanu 19

Johanu 19:26-32