Johanu 18:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tún kígbe pé, “Òun kọ́! Baraba ni kí o dá sílẹ̀!” (Ọlọ́ṣà paraku ni Baraba yìí.)

Johanu 18

Johanu 18:31-40