Johanu 18:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Pilatu bi í pé, “Kí ni òtítọ́?”Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, ó tún jáde lọ sọ́dọ̀ àwọn Juu, ó sọ fún wọn pé, “Èmi kò rí ẹ̀bi kankan tí ó jẹ.

Johanu 18

Johanu 18:37-40