Johanu 18:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Pilatu dáhùn pé, “Èmi í ṣe Juu bí? Àwọn eniyan rẹ ati àwọn olórí alufaa ni wọ́n fà ọ́ wá sọ́dọ̀ mi. Kí ni o ṣe?”

Johanu 18

Johanu 18:33-40