Johanu 18:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Bí ọkunrin yìí kò bá ṣe nǹkan burúkú ni, a kì bá tí fà á lé ọ lọ́wọ́ fún ìdájọ́.”

Johanu 18

Johanu 18:22-39