Johanu 18:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá sọ fún Peteru pé, “Ti idà rẹ bọ inú àkọ̀. Àbí kí n má jẹ ìrora ńlá tí Baba ti yàn fún mi ni?”

Johanu 18

Johanu 18:10-18