Johanu 17:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, Baba, jẹ́ kí ògo rẹ hàn lára mi; àní kí irú ògo tí mo ti ní pẹlu rẹ kí a tó dá ayé tún hàn lára mi.

Johanu 17

Johanu 17:1-10