Johanu 17:15 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò bẹ̀bẹ̀ pé kí o mú wọn kúrò ninu ayé. Ẹ̀bẹ̀ mi ni pé kí o pa wọ́n mọ́ kúrò lọ́wọ́ Èṣù.

Johanu 17

Johanu 17:6-18