Johanu 16:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó bá dé, yóo fi han aráyé pé wọ́n ti ṣìnà ninu èrò wọn nípa ẹ̀ṣẹ̀, ati nípa òdodo, ati nípa ìdájọ́ Ọlọrun.

Johanu 16

Johanu 16:1-13