Johanu 16:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá láti ọ̀dọ̀ Baba, mo jáde wá sinu ayé, n óo tún fi ayé sílẹ̀ láti lọ sọ́dọ̀ Baba.”

Johanu 16

Johanu 16:19-33