Johanu 16:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tún ń sọ pé, “Kí ni ìtumọ̀ ‘Láìpẹ́’ tí ó ń wí yìí? Ohun tí ó ń sọ kò yé wa.”

Johanu 16

Johanu 16:11-24