Johanu 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Tèmi ni ohun gbogbo tí Baba ní. Ìdí nìyí ti mo ṣe sọ pé ohun tí ó bá gbà láti ọ̀dọ̀ mi ni yóo sọ fun yín.

Johanu 16

Johanu 16:14-16