Johanu 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbà mí gbọ́ pé mo wà ninu Baba ati pé Baba wà ninu mi. Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ẹ gbà mí gbọ́ nítorí iṣẹ́ wọnyi.

Johanu 14

Johanu 14:6-12