Johanu 13:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ Simoni Peteru, Peteru bi í pé, “Oluwa, ìwọ ni o fẹ́ fọ ẹsẹ̀ mi?”

Johanu 13

Johanu 13:1-13