Johanu 13:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Simoni Peteru bi í pé, “Oluwa, níbo ni ò ń lọ?”Jesu dá a lóhùn pé, “Níbi tí mò ń lọ, ìwọ kò lè tẹ̀lé mi nisinsinyii, ṣugbọn nígbà tí ó bá yá, ìwọ óo tẹ̀lé mi.”

Johanu 13

Johanu 13:30-38