Johanu 13:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Judasi jáde, Jesu wí pé, “Nisinsinyii ni ògo Ọmọ-Eniyan wá yọ. Ògo Ọlọrun pàápàá yọ lára Ọmọ-Eniyan.

Johanu 13

Johanu 13:29-38