Johanu 13:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wí fun yín nisinsinyii kí ó tó ṣẹlẹ̀, kí ẹ lè mọ ẹni tí èmi í ṣe nígbà tí ó bá ti ṣẹlẹ̀ tán.

Johanu 13

Johanu 13:16-28