Johanu 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí èmi Oluwa ati Olùkọ́ni yín bá fọ ẹsẹ̀ yín, ó yẹ kí ẹ máa fọ ẹsẹ̀ ẹnìkejì yín.

Johanu 13

Johanu 13:8-17