Johanu 12:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá sinu ayé bí ìmọ́lẹ̀, kí ẹni tí ó bá gbà mí gbọ́ má baà wà ninu òkùnkùn.

Johanu 12

Johanu 12:45-50