Johanu 12:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá kígbe pé, “Ẹni tí ó bá gbà mí gbọ́, kì í ṣe èmi ni ó gbàgbọ́ bíkòṣe ẹni tí ó rán mi níṣẹ́.

Johanu 12

Johanu 12:40-46