Johanu 12:40 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ojú wọn ti fọ́,ọkàn wọn sì ti le;kí wọn má baà fi ojú wọn ríran,kí òye má baà yé wọn.Kí wọn má baà yipada,kí n má baà wò wọ́n sàn.”

Johanu 12

Johanu 12:37-47