Johanu 12:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Jesu ti ṣe ọpọlọpọ iṣẹ́ ìyanu lójú wọn, sibẹ wọn kò gbà á gbọ́.

Johanu 12

Johanu 12:34-39