Johanu 12:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lọ sọ́dọ̀ Filipi tí ó jẹ́ ará Bẹtisaida, ìlú kan ní Galili, wọ́n sọ fún un pé, “Alàgbà, a fẹ́ rí Jesu.”

Johanu 12

Johanu 12:20-28