Johanu 11:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí alufaa ati àwọn Farisi ti pàṣẹ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá mọ ibi tí Jesu wà, kí ó wá sọ, kí wọ́n lè mú un.

Johanu 11

Johanu 11:52-57