Johanu 11:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí alufaa ati àwọn Farisi bá pe ìgbìmọ̀, wọ́n ní, “Kí ni a óo ṣe o, nítorí ọkunrin yìí ń ṣe iṣẹ́ ìyanu pupọ?

Johanu 11

Johanu 11:46-51