Johanu 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu gbọ́, ó ní, “Àìsàn yìí kì í ṣe ti ikú, fún ògo Ọlọrun ni, kí á lè ṣe Ọmọ Ọlọrun lógo nípa rẹ̀ ni.”

Johanu 11

Johanu 11:1-8