Johanu 11:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu rí i tí ó ń sunkún, tí àwọn Juu tí ó bá a jáde tún ń sunkún, orí rẹ̀ wú, ọkàn rẹ̀ wá bàjẹ́.

Johanu 11

Johanu 11:26-39