Johanu 11:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹni tí ó bá wà láàyè, tí ó bá gbà mí gbọ́, kò ní kú laelae. Ǹjẹ́ o gba èyí gbọ́?”

Johanu 11

Johanu 11:22-34