Johanu 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Mata gbọ́ pé Jesu ń bọ̀, ó jáde lọ pàdé rẹ̀. Ṣugbọn Maria jókòó ninu ilé.

Johanu 11

Johanu 11:17-27