Johanu 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí gbogbo àwọn aguntan rẹ̀ bá jáde, a máa lọ níwájú wọn, àwọn aguntan a sì tẹ̀lé e nítorí wọ́n mọ ohùn rẹ̀.

Johanu 10

Johanu 10:1-7