Johanu 10:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fún wọn ní ìyè ainipẹkun, wọn kò lè kú mọ́ laelae, bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kò lè já wọn gbà mọ́ mi lọ́wọ́.

Johanu 10

Johanu 10:25-32