Johanu 10:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Mo sọ fun yín, ẹ kò gbàgbọ́. Iṣẹ́ tí mò ń ṣe ní orúkọ Baba mi ń jẹ́rìí mi,

Johanu 10

Johanu 10:16-26