Johanu 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ ninu wọn sọ pé, “Ó ní ẹ̀mí èṣù, orí rẹ̀ ti dàrú. Kí ni ẹ̀ ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí?”

Johanu 10

Johanu 10:10-26