Johanu 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá tún bèèrè pé, “Ó dára, ta ni ọ́? Ó yẹ kí á lè rí èsì mú pada fún àwọn tí wọ́n rán wa wá. Kí ni o sọ nípa ara rẹ?”

Johanu 1

Johanu 1:13-28