Johanu 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípasẹ̀ Mose ni a ti fún wa ní Òfin, ṣugbọn nípasẹ Jesu Kristi ni oore-ọ̀fẹ́ ati òtítọ́ ti wá.

Johanu 1

Johanu 1:8-22