Johanu 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

A kò bí wọn bí eniyan ṣe ń bímọ nípa ìfẹ́ ara tabi ìfẹ́ eniyan, ṣugbọn nípa ìfẹ́ Ọlọrun ni a bí wọn.

Johanu 1

Johanu 1:11-14