Johanu Kinni 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹni tí ó bá gbàgbọ́ pé Jesu ni Mesaya, a bí i láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun. Gbogbo ẹni tí ó bá fẹ́ràn baba yóo fẹ́ràn Ọmọ rẹ̀.

Johanu Kinni 5

Johanu Kinni 5:1-9