Johanu Kinni 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà tí Ọlọrun fi fi ìfẹ́ tí ó ní sí wa hàn ni pé ó ti rán ààyò ọmọ rẹ̀ wá sáyé kí á lè ní ìgbàlà nípasẹ̀ rẹ̀.

Johanu Kinni 4

Johanu Kinni 4:8-10