Johanu Kinni 4:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́wọ́ pé Ọmọ Ọlọrun ni Jesu, Ọlọrun ń gbé inú rẹ̀, òun náà sì ń gbé inú Ọlọrun.

Johanu Kinni 4

Johanu Kinni 4:6-21