Johanu Kinni 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Olùfẹ́, bí Ọlọrun bá fẹ́ràn wa tó báyìí, ó yẹ kí àwa náà fẹ́ràn ọmọnikeji wa.

Johanu Kinni 4

Johanu Kinni 4:7-12