Johanu Kinni 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ọmọde, ẹ má jẹ́ kí ìfẹ́ wa jẹ́ ti ọ̀rọ̀ ẹnu tabi ti ètè lásán; ṣugbọn kí ó jẹ́ ti ìwà ati ti òtítọ́.

Johanu Kinni 3

Johanu Kinni 3:15-20