Johanu Kinni 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà tí a fi mọ ìfẹ́ nìyí, pé ẹnìkan fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ fún wa. Nítorí náà, ó yẹ kí àwa náà fi ẹ̀mí wa lélẹ̀ fún àwọn ará.

Johanu Kinni 3

Johanu Kinni 3:15-24