Johanu Kinni 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwa mọ̀ pé a ti rékọjá láti inú ikú sí inú ìyè, nítorí a fẹ́ràn àwọn arakunrin. Ẹni tí kò bá ní ìfẹ́ wà ninu ikú.

Johanu Kinni 3

Johanu Kinni 3:4-15