Johanu Kinni 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí á má dàbí Kaini tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Èṣù, tí ó pa arakunrin rẹ̀. Kí ló dé tí ó fi pa á? Nítorí iṣẹ́ tirẹ̀ burú, ṣugbọn ti arakunrin rẹ̀ dára.

Johanu Kinni 3

Johanu Kinni 3:8-16