Johanu Kinni 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Olùfẹ́, kì í ṣe òfin titun ni mò ń kọ si yín. Òfin àtijọ́ tí ẹ ti níláti ìbẹ̀rẹ̀ ni. Òfin àtijọ́ náà ni ọ̀rọ̀ tí ẹ ti gbọ́.

Johanu Kinni 2

Johanu Kinni 2:4-14