Johanu Kinni 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dájú pé ìfẹ́ Ọlọrun ti di pípé ninu ẹnikẹ́ni tí ó bá ń pa ọ̀rọ̀ rẹ̀ mọ́. Ọ̀nà tí a fi mọ̀ pé a wà ninu rẹ̀ nìyí

Johanu Kinni 2

Johanu Kinni 2:4-11